Gẹn 37:3 YCE

3 Israeli si fẹ́ Josefu jù gbogbo awọn ọmọ rẹ̀ lọ, nitori ti iṣe ọmọ ogbó rẹ̀; o si dá ẹ̀wu alarabara aṣọ fun u.

Ka pipe ipin Gẹn 37

Wo Gẹn 37:3 ni o tọ