Gẹn 38:20 YCE

20 Judah si rán ọmọ ewurẹ na lati ọwọ́ ọ̀rẹ́ rẹ̀, ara Adullamu na lọ, lati gbà ògo nì wá lọwọ obinrin na: ṣugbọn on kò ri i.

Ka pipe ipin Gẹn 38

Wo Gẹn 38:20 ni o tọ