Gẹn 4:4 YCE

4 Ati Abeli, on pẹlu mu ninu akọbi ẹran-ọ̀sin ani ninu awọn ti o sanra. OLUWA si fi ojurere wò Abeli ati ọrẹ rẹ̀;

Ka pipe ipin Gẹn 4

Wo Gẹn 4:4 ni o tọ