Gẹn 40:15 YCE

15 Nitõtọ jíji li a jí mi tà lati ilẹ awọn Heberu wá: ati nihinyi pẹlu, emi kò ṣe nkan ti nwọn fi fi mi sinu ihò-túbu yi.

Ka pipe ipin Gẹn 40

Wo Gẹn 40:15 ni o tọ