34 Ki Farao ki o ṣe eyi, ki o si yàn awọn alabojuto si ilẹ yi, ki nwọn ki o si gbà idamarun ni ilẹ Egipti li ọdún meje ọ̀pọ nì.
Ka pipe ipin Gẹn 41
Wo Gẹn 41:34 ni o tọ