Gẹn 41:38 YCE

38 Farao si wi fun awọn ọmọ-ọdọ rẹ̀ pe, A ha le ri ẹnikan bi irú eyi, ọkunrin ti Ẹmi Ọlọrun mbẹ ninu rẹ̀?

Ka pipe ipin Gẹn 41

Wo Gẹn 41:38 ni o tọ