Gẹn 41:45 YCE

45 Farao si sọ orukọ Josefu ni Safnati-paanea; o si fi Asenati fun u li aya, ọmọbinrin Potifera, alufa Oni. Josefu si jade lọ si ori ilẹ Egipti.

Ka pipe ipin Gẹn 41

Wo Gẹn 41:45 ni o tọ