Gẹn 42:35 YCE

35 O si ṣe, bi nwọn ti ndà àpo wọn, wò o, ìdi owo olukuluku wà ninu àpo rẹ̀: nigbati awọn ati baba wọn si ri ìdi owo wọnni, ẹ̀ru bà wọn.

Ka pipe ipin Gẹn 42

Wo Gẹn 42:35 ni o tọ