Gẹn 42:4 YCE

4 Ṣugbọn Jakobu kò rán Benjamini arakunrin Josefu pẹlu awọn arakunrin rẹ̀; nitori ti o wipe, Ki ibi ki o má ba bá a.

Ka pipe ipin Gẹn 42

Wo Gẹn 42:4 ni o tọ