Gẹn 42:6 YCE

6 Josefu li o si ṣe balẹ ilẹ na, on li o ntà fun gbogbo awọn enia ilẹ na; awọn arakunrin Josefu si wá, nwọn si tẹ̀ ori wọn ba fun u, nwọn dojubolẹ.

Ka pipe ipin Gẹn 42

Wo Gẹn 42:6 ni o tọ