Gẹn 43:22 YCE

22 Owo miran li awa si mú li ọwọ́ wa sọkalẹ wá lati rà onjẹ: awa kò mọ̀ ẹniti o fi owo wa sinu àpo wa.

Ka pipe ipin Gẹn 43

Wo Gẹn 43:22 ni o tọ