Gẹn 44:32 YCE

32 Nitori iranṣẹ rẹ li o ṣe onigbọwọ ọmọde na fun baba mi wipe, Bi emi kò ba mú u tọ̀ ọ wá, emi ni o gbà ẹbi na lọdọ baba mi lailai.

Ka pipe ipin Gẹn 44

Wo Gẹn 44:32 ni o tọ