Gẹn 46:32 YCE

32 Oluṣọ-agutan si li awọn ọkunrin na, ẹran sisìn ni iṣẹ wọn; nwọn si dà agbo-ẹran ati ọwọ́-ẹran wọn wá, ati ohun gbogbo ti nwọn ní.

Ka pipe ipin Gẹn 46

Wo Gẹn 46:32 ni o tọ