Gẹn 47:20 YCE

20 Bẹ̃ni Josefu rà gbogbo ilẹ Egipti fun Farao; nitori olukuluku awọn ara Egipti li o tà oko rẹ̀, nitori ti ìyan na mú wọn: ilẹ si di ti Farao.

Ka pipe ipin Gẹn 47

Wo Gẹn 47:20 ni o tọ