Gẹn 49:29 YCE

29 O si kìlọ fun wọn, o si sọ fun wọn pe, A o kó mi jọ pọ̀ pẹlu awọn enia mi: ẹ sin mi pẹlu awọn baba mi ni ihò ti o mbẹ li oko Efroni ara Hitti.

Ka pipe ipin Gẹn 49

Wo Gẹn 49:29 ni o tọ