Gẹn 49:7 YCE

7 Ifibú ni ibinu wọn, nitori ti o rorò; ati ikannu wọn, nitori ti o ní ìka: emi o pin wọn ni Jakobu, emi o si tú wọn ká ni Israeli.

Ka pipe ipin Gẹn 49

Wo Gẹn 49:7 ni o tọ