Gẹn 50:23 YCE

23 Josefu si ri awọn ọmọloju Efraimu ti iran kẹta; awọn ọmọ Makiri, ọmọ Manasse li a si gbé kà ori ẽkun Josefu pẹlu.

Ka pipe ipin Gẹn 50

Wo Gẹn 50:23 ni o tọ