Gẹn 6:18 YCE

18 Ṣugbọn iwọ li emi o ba dá majẹmu mi; iwọ o si wọ̀ inu ọkọ̀ na, iwọ ati awọn ọmọ rẹ, ati aya rẹ, ati awọn aya awọn ọmọ rẹ pẹlu rẹ.

Ka pipe ipin Gẹn 6

Wo Gẹn 6:18 ni o tọ