Gẹn 9:1 YCE

1 ỌLỌRUN si sure fun Noa, ati fun awọn ọmọ rẹ̀, o si wi fun wọn pe, Ẹ ma bí si i, ẹ si ma rẹ̀, ki ẹ si kún aiye.

Ka pipe ipin Gẹn 9

Wo Gẹn 9:1 ni o tọ