Lef 11:31 YCE

31 Wọnyi li alaimọ́ fun nyin ninu gbogbo ohun ti nrakò: ẹnikẹni ti o ba farakàn okú wọn, ki o jẹ́ alaimọ́ titi di aṣalẹ.

Ka pipe ipin Lef 11

Wo Lef 11:31 ni o tọ