Lef 13:13 YCE

13 Nigbana ni ki alufa ki o wò o: si kiyesi i, bi ẹ̀tẹ na ba bò gbogbo ara rẹ̀, ki o pè àlarun na ni mimọ́; gbogbo rẹ̀ di funfun: mimọ́ li on.

Ka pipe ipin Lef 13

Wo Lef 13:13 ni o tọ