54 Nigbana ni ki alufa ki o paṣẹ ki nwọn ki o fọ̀ ohun na ninu eyiti àrun na gbé wà, ki o si sé e mọ́ ni ijọ meje si i.
Ka pipe ipin Lef 13
Wo Lef 13:54 ni o tọ