Lef 13:8 YCE

8 Alufa yio wò o, kiyesi i, apá na ràn li awọ ara rẹ̀, nigbana ni ki alufa ki o pè e li alaimọ́: ẹ̀tẹ ni.

Ka pipe ipin Lef 13

Wo Lef 13:8 ni o tọ