Lef 14:7 YCE

7 Ki o si fi wọ́n ẹniti a o wẹ̀numọ́ kuro ninu ẹ̀tẹ nigba meje, ki o si pè e ni mimọ́, ki o si jọwọ ẹiyẹ alãye nì lọwọ lọ si gbangba oko.

Ka pipe ipin Lef 14

Wo Lef 14:7 ni o tọ