Lef 15:2 YCE

2 Sọ fun awọn ọmọ Israeli, ki o si wi fun wọn pe, Nigbati ẹnikan ba ní àrun isun lara rẹ̀, nitori isun rẹ̀ alaimọ́ li on.

Ka pipe ipin Lef 15

Wo Lef 15:2 ni o tọ