Lef 16:23 YCE

23 Ki Aaroni ki o si wá sinu agọ́ ajọ, ki o si bọ́ aṣọ ọ̀gbọ wọnni silẹ, ti o múwọ̀ nigbati o wọ̀ ibi mimọ́ lọ, ki o si fi wọn sibẹ̀:

Ka pipe ipin Lef 16

Wo Lef 16:23 ni o tọ