Lef 17:7 YCE

7 Ki nwọn ki o má si ṣe ru ẹbọ wọn si obukọ mọ́, ti nwọn ti ntọ̀ lẹhin ṣe àgbere. Eyi ni yio ma ṣe ìlana lailai fun wọn ni iran-iran wọn.

Ka pipe ipin Lef 17

Wo Lef 17:7 ni o tọ