Lef 2:10 YCE

10 Eyiti o si kù ninu ẹbọ ohunjijẹ, ki o jẹ́ ti Aaroni, ati ti awọn ọmọ rẹ̀: ohun mimọ́ julọ ni, ọrẹ-ẹbọ OLUWA ti a fi iná ṣe.

Ka pipe ipin Lef 2

Wo Lef 2:10 ni o tọ