Lef 20:14 YCE

14 Ati ọkunrin ti o ba fẹ́ obinrin ati iya rẹ̀, ìwabuburu ni: iná li a o fi sun wọn, ati on ati awọn; ki ìwabuburu ki o má ṣe sí lãrin nyin.

Ka pipe ipin Lef 20

Wo Lef 20:14 ni o tọ