Lef 20:16 YCE

16 Bi obinrin kan ba si sunmọ ẹranko kan, lati dubulẹ tì i, ki iwọ ki o pa obinrin na, ati ẹranko na: pipa ni ki a pa wọn; ẹ̀jẹ wọn yio wà lori wọn.

Ka pipe ipin Lef 20

Wo Lef 20:16 ni o tọ