Lef 20:23 YCE

23 Ẹnyin kò si gbọdọ rìn ninu ìlana orilẹ-ède, ti emi lé jade kuro niwaju nyin: nitoriti nwọn ṣe gbogbo wọnyi, nitorina ni mo ṣe korira wọn.

Ka pipe ipin Lef 20

Wo Lef 20:23 ni o tọ