Lef 25:25 YCE

25 Bi arakunrin rẹ ba di talakà, ti o ba si tà ninu ilẹ-iní rẹ̀, bi ẹnikan ninu awọn ibatan rẹ̀ ba si wá lati rà a, njẹ ki o rà eyiti arakunrin rẹ̀ ti tà pada.

Ka pipe ipin Lef 25

Wo Lef 25:25 ni o tọ