Lef 25:41 YCE

41 Nigbana ni ki o lọ kuro lọdọ rẹ, ati on ati awọn ọmọ rẹ̀ pẹlu rẹ̀, ki o si pada lọ si idile rẹ̀, ati si ilẹ-iní awọn baba rẹ̀ ni ki o pada si.

Ka pipe ipin Lef 25

Wo Lef 25:41 ni o tọ