Lef 4:17 YCE

17 Ki alufa na ki o si tẹ̀ iká rẹ̀ bọ̀ inu ẹ̀jẹ na, ki o si wọ́n ọ nigba meje niwaju OLUWA, niwaju aṣọ-ikele.

Ka pipe ipin Lef 4

Wo Lef 4:17 ni o tọ