Lef 6:22 YCE

22 Ati alufa ninu awọn ọmọ rẹ̀ ti a fi oróro yàn ni ipò rẹ̀ ni ki o ru u: aṣẹ titilai ni fun OLUWA, sisun ni ki a sun u patapata.

Ka pipe ipin Lef 6

Wo Lef 6:22 ni o tọ