Lef 7:29 YCE

29 Sọ fun awọn ọmọ Israeli pe, Ẹniti o ba ru ẹbọ alafia rẹ̀ si OLUWA, ki o mú ọrẹ-ẹbọ rẹ̀ tọ̀ OLUWA wá ninu ẹbọ alafia rẹ̀:

Ka pipe ipin Lef 7

Wo Lef 7:29 ni o tọ