Lef 8:25 YCE

25 O si mú ọrá na, ati ìru ti o lọrá, ati gbogbo ọrá ti o mbẹ lara ifun, ati àwọn ti o bò ẹ̀dọ, ati iwe mejeji, ati ọrá wọn, ati itan ọtún:

Ka pipe ipin Lef 8

Wo Lef 8:25 ni o tọ