Lef 8:28 YCE

28 Mose si gbà wọn li ọwọ́ wọn, o si sun wọn lori pẹpẹ li ẹbọ sisun: ìyasimimọ́ ni nwọn fun õrùn didùn: ẹbọ ti a fi iná ṣe ni si OLUWA.

Ka pipe ipin Lef 8

Wo Lef 8:28 ni o tọ