Lef 9:24 YCE

24 Iná kan si ti ọdọ OLUWA jade wá, o si jó ẹbọ sisun ati ọrá ori pẹpẹ na; nigbati gbogbo awọn enia ri i, nwọn hó kùhu, nwọn si dojubolẹ.

Ka pipe ipin Lef 9

Wo Lef 9:24 ni o tọ