Num 1:4 YCE

4 Ki ọkunrin kọkan lati inu olukuluku ẹ̀ya ki o si wà pẹlu nyin; ki olukuluku jẹ́ olori ile awọn baba rẹ̀.

Ka pipe ipin Num 1

Wo Num 1:4 ni o tọ