Num 13:18 YCE

18 Ki ẹnyin si wò ilẹ na, bi o ti ri; ati awọn enia ti ngbé inu rẹ̀, bi nwọn ṣe alagbara tabi alailagbara, bi diẹ ni nwọn, tabi pupọ̀;

Ka pipe ipin Num 13

Wo Num 13:18 ni o tọ