Num 13:27 YCE

27 Nwọn si rò fun u, nwọn si wipe, Awa dé ilẹ na nibiti iwọ gbé rán wa lọ, nitõtọ li o nṣàn fun warà ati fun oyin; eyi si li eso rẹ̀.

Ka pipe ipin Num 13

Wo Num 13:27 ni o tọ