Num 14:45 YCE

45 Nigbana li awọn ara Amaleki sọkalẹ wá, ati awọn ara Kenaani ti ngbé ori-òke na, nwọn si kọlù wọn nwọn si ṣẹ́ wọn titi dé Horma.

Ka pipe ipin Num 14

Wo Num 14:45 ni o tọ