Num 15:26 YCE

26 A o si darijì gbogbo ijọ awọn ọmọ Israeli, ati alejò ti iṣe atipo lọdọ wọn; nitoripe gbogbo enia wà li aimọ̀.

Ka pipe ipin Num 15

Wo Num 15:26 ni o tọ