Num 22:12 YCE

12 Ọlọrun si wi fun Balaamu pe, Iwọ kò gbọdọ bá wọn lọ; iwọ kò gbọdọ fi awọn enia na bú: nitoripe ẹni ibukún ni nwọn.

Ka pipe ipin Num 22

Wo Num 22:12 ni o tọ