Num 22:36 YCE

36 Nigbati Balaki gbọ́ pe Balaamu dé, o jade lọ ipade rẹ̀ si Ilu Moabu, ti mbẹ ni àgbegbe Arnoni, ti iṣe ipẹkun ipinlẹ na.

Ka pipe ipin Num 22

Wo Num 22:36 ni o tọ