11 Ṣugbọn awọn ọmọ Kora kò kú.
12 Awọn ọmọ Simeoni bi idile wọn: ti Nemueli, idile Nemueli: ti Jamini, idile Jamini: ti Jakini, idile Jakini:
13 Ti Sera, idile Sera: ti Ṣaulu, idile Ṣaulu.
14 Wọnyi ni idile awọn ọmọ Simeoni, ẹgba mọkanla o le igba.
15 Awọn ọmọ Gadi bi idile wọn: ti Sefoni, idile Sefoni: ti Haggi, idile Haggi: ti Ṣuni, idile Ṣuni:
16 Ti Osni, idile Osni: ti Eri, idile Eri:
17 Ti Arodu, idile Arodu: ti Areli, idile Areli.