Num 26:20 YCE

20 Ati awọn ọmọ Juda gẹgẹ bi idile wọn; ti Ṣela, idile Ṣela: ti Peresi, idile Peresi: ti Sera, idile Sera.

Ka pipe ipin Num 26

Wo Num 26:20 ni o tọ