Num 28:28 YCE

28 Ati ẹbọ ohunjijẹ wọn, iyẹfun ti a fi oróro pò, idamẹwa mẹta òṣuwọn fun akọmalu kan, ati idamẹwa meji òṣuwọn fun àgbo kan,

Ka pipe ipin Num 28

Wo Num 28:28 ni o tọ