Num 29:16 YCE

16 Ati obukọ kan fun ẹbọ ẹ̀ṣẹ; pẹlu ẹbọ sisun igbagbogbo, ẹbọ ohunjijẹ rẹ̀, ati ẹbọ ohunmimu rẹ̀.

Ka pipe ipin Num 29

Wo Num 29:16 ni o tọ